|
Post by Belmot on May 18, 2016 14:49:04 GMT
Gbogbo eni ti oba fe iyawo ni iju, yo se'ana ebora.
(If you marry a woman in the forest, you should be ready to be an inlaw of the deity).
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 14:52:15 GMT
Agbon (wasp) nse, Oyin (bee) naa nse, bee sini oju oloko re kondu-kondu.
(both wasp and bee were claiming innocence , yet the farmer has swollen face).
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 14:54:32 GMT
Baba ọmọ ló n gbọmọ, ìrùkẹ̀rẹ̀ lo n gbọmọ Ọrunmila; b'ódò bá kún tan òmùwẹ̀ laa pè kó wa gbani.
(A father of a child it is that rescues the child just as it is the ceremonial horsetail that resues the Orunmila (Ifa) worshipper; when the tide is very high it is an expert swimmer one calls upon to rescue one.)
|
|
|
Post by ajanaku on May 18, 2016 14:55:09 GMT
Belmot , could you please interpret the proverbs posted for better understanding. The absence of the marks ( ami oke, ami aarin ati ami isale) impedes the ability to understand them. Thanks, baba!
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:13:35 GMT
Ibi ti a fi iyo si,ni i se omi si.
(It is where we put salt that it turns to water)
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:18:42 GMT
Bi a ba yin ireke to dun, o ye ka yin eti odo to hu
(If we praise the sugarcane for its sweetness,so we should praise the riverbank as well).
|
|
|
Post by ajanaku on May 18, 2016 15:20:26 GMT
Igba o lọ bi orere. Aye o tan lọ bi ọpa ibọn...
Time is fleeting. Life ends like the barrel of a gun.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:42:46 GMT
Orin ti kò bá ṣòroó dá kì í ṣòroó gbè: ti wọn bá sọ pe "Sáñsálùbọ́" àá si dahun pe "Pẹẹrẹpẹ".
( A simple song only requires a simple chorus: if they lead with "how do you spread yam/plantain slices to dry?" you chorus in a way that demonstrates throwing things on the ground to dry!
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:43:09 GMT
Orin ti kò bá ṣòroó dá kì í ṣòroó gbè: ti wọn bá sọ pe "Sáñsálùbọ́" àá si dahun pe "Pẹẹrẹpẹ".
( A simple song only requires a simple chorus: if they lead with "how do you spread yam/plantain slices to dry?" you chorus in a way that demonstrates throwing things on the ground to dry)
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:46:10 GMT
Jojo agbo nii mu agbo n'iyi, ola baba nii mu omo yan.
(The mane gives the ram its dignity; and the father's respectability enables the child to walk with confidence.)
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:48:25 GMT
Igi Ogede ni o wo koko (Cocoa) san ki o to di igi buruku.
(It is the banana tree that heals the cocoa tree before it becomes bad.)
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:51:07 GMT
Belmot , could you please interpret the proverbs posted for better understanding. The absence of the marks ( ami oke, ami aarin ati ami isale) impedes the ability to understand them. Thanks, baba! You can also help with some translation if you can. Thanks.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:54:22 GMT
Òmùgọ̀ èèyàn ní ḿbóbìnrin mulẹ̀, ọjọ́ tóbìnrín bá mawo lawó bàjẹ́. Hahahaha ..... Can you help with translations too?
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 15:56:16 GMT
Bi òwe, bi òwe ni a ńlu ìlu àkìndìgbó. Ologbón ni njo, òmòràn ni o mo Idi e.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 16:03:15 GMT
Bó já, ma a tun so, kò ki n gùn to ti tẹlẹ mọ.
(If it breaks you will re-tie together but the length will never be the same again.)
|
|