|
Post by skebe on Jun 20, 2017 20:18:43 GMT
O m'umi ranti owe Yoruba kan to wipe ... Ọmọde gbọn, agba gbọn, l'afi d'alẹ Ifẹ. Hello stranger Ta lo le e salo? ------------------- Ife ko Ife. Awon omo Yoruba ma n pe eni ti won feran ni "ololufe mi". Mi mo owe ati akanlo ede Yoruba, wu mi lopolopo, ki ba daa ra ki o ma jeyo ninu gbolohun wa
|
|
|
Post by ajanaku on Jun 20, 2017 20:25:09 GMT
O m'umi ranti owe Yoruba kan to wipe ... Ọmọde gbọn, agba gbọn, l'afi d'alẹ Ifẹ. Hello stranger Ta lo le e salo? ------------------- Ife ko Ife. Awon omo Yoruba ma n pe eni ti won feran ni "ololufe mi". Stranger? Salo? I've always been here. It's been long I commented, though. The Ifẹ I referred to is the town in Osun state and not the "Love" variation. The proverb loosely translates thus: The contribution of the elderly and the kids is what made the town of Ifẹ what it is today ... I guess you've never heard it before. SMH ....................................................................................................................................................................................................... Ololufẹ mi otitọ kan ṣo ṣo ni Iya to bi mi l'ọmọ. Ifẹ re si mi o l'afiwe. Bẹẹni ko si ni abawọn kan kan. (My truest love is my Mama. Her love for me is incomparable ... and without blemishes)
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 21, 2017 19:51:07 GMT
ajanaku, Oya start a sentence with Kan, lemme see. -_-
|
|
|
Post by ajanaku on Jun 21, 2017 21:32:17 GMT
Her Highness , Kan mi pẹlu ifẹ ẹ rẹ, ki aiye mi b'aale dun bi oyin ... (Touch me with your love, so as to make my life as sweet as honey)
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 21, 2017 22:57:15 GMT
Her Highness , Kan mi pẹlu ifẹ ẹ rẹ, ki aiye mi b'aale dun bi oyin ... (Touch me with your love, so as to make my life as sweet as honey) Ahh ok. Oyin ni mo ma n fi sinu bournvita mi lati fi je agege buredi. Sugbon ni ekookan, o ma n wu mi lati je iyan ati egusi. Oru ounje wo lo le se?
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 21, 2017 23:00:27 GMT
Uncle skebe , must we invite you all the time?
|
|
|
Post by skebe on Jun 21, 2017 23:51:11 GMT
Uncle skebe , must we invite you all the time? Haha, auntie mi, rara o, AYS
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 22, 2017 0:02:52 GMT
Uncle skebe , must we invite you all the time? Haha, auntie mi, rara o, AYS Se e ni ko wa ni Yoruba ilu yin ni?
|
|
|
Post by ajanaku on Jun 22, 2017 5:02:52 GMT
Her Highness , Kan mi pẹlu ifẹ ẹ rẹ, ki aiye mi b'aale dun bi oyin ... (Touch me with your love, so as to make my life as sweet as honey) Ahh ok. Oyin ni mo ma n fi sinu bournvita mi lati fi je agege buredi. Sugbon ni ekookan, o ma n wu mi lati je iyan ati egusi. Oru ounje wo lo le se? Rules:2. You must write in Yoruba
What in Gawd's world is "agege buredi"? It's either the "pidginized" version "Agege bread" or the correct Yoruba version, "Buredi Agege". Ekookan should be "Ekan kan" ... SMH .................................................................................................................................................................................................... Se ounjẹ kẹ? Emi o kii n se ounjẹ o. Mi o mọ ounje se rara. Mo ma l'o n jẹun n'ita ni ti ebi ba n pa mi. (Cook? I don't cook. I can't cook at all. I eat out when I'm hungry)
|
|
|
Post by skebe on Jun 22, 2017 7:37:30 GMT
Haha, auntie mi, rara o, AYS Se e ni ko wa ni Yoruba ilu yin ni? Ni ilu wa Ibadan, ewa Yoruba wa ma n jeyo ni si so, di poo ni ki ko
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 22, 2017 18:29:15 GMT
Ahh ok. Oyin ni mo ma n fi sinu bournvita mi lati fi je agege buredi. Sugbon ni ekookan, o ma n wu mi lati je iyan ati egusi. Oru ounje wo lo le se? Rules:2. You must write in Yoruba
What in Gawd's world is "agege buredi"?
It's either the "pidginized" version "Agege bread" or the correct Yoruba version, "Buredi Agege".
Ekookan should be "Ekan kan" ...SMH .................................................................................................................................................................................................... Se ounjẹ kẹ? Emi o kii n se ounjẹ o. Mi o mọ ounje se rara. Mo ma l'o n jẹun n'ita ni ti ebi ba n pa mi. (Cook? I don't cook. I can't cook at all. I eat out when I'm hungry) Awon haters ti de! Lol you're right tho. Thanks for the correction.
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 22, 2017 18:32:49 GMT
Se e ni ko wa ni Yoruba ilu yin ni? Ni ilu wa Ibadan, ewa Yoruba wa ma n jeyo ni si so, di poo ni ki ko Ko r'emi lati so pe omo Naijiriya ni mi nigba ti awon ti a dibo fun ko toju wa. Uncle Skebe, N'ibo le wa nisisiyi?
|
|
|
Post by skebe on Jun 22, 2017 18:49:55 GMT
Ni ilu wa Ibadan, ewa Yoruba wa ma n jeyo ni si so, di poo ni ki ko Ko r'emi lati so pe omo Naijiriya ni mi nigba ti awon ti a dibo fun ko toju wa. Uncle Skebe, N'ibo le wa nisisiyi? Nisisiyi, mo wa ni ilu Eko. Ni Eko ni ikoko obe mi wa
|
|
|
Post by Her Highness on Jun 22, 2017 18:52:20 GMT
Ko r'emi lati so pe omo Naijiriya ni mi nigba ti awon ti a dibo fun ko toju wa. Uncle Skebe, N'ibo le wa nisisiyi? Nisisiyi, mo wa ni ilu Eko. Ni Eko ni ikoko obe mi wa wa, ogbeni, kini itumo ikoko obe? Ewo lo n je Ilu Eko?
|
|
|
Post by skebe on Jun 22, 2017 19:03:44 GMT
Nisisiyi, mo wa ni ilu Eko. Ni Eko ni ikoko obe mi wa wa, ogbeni, kini itumo ikoko obe? Ewo lo n je Ilu Eko? Eko je oruko ti a le fi pe Lagos, amo, Lagos Island gan gan lo n je Eko Ikoko - pot Obe - soup Ikoko obe - pot of soup - means of feeding Ilu - city Eko - Lagos
|
|