|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:13:31 GMT
B'ówó ti mọ loogun n mọ. (ie the amount of money [one has] determines the quantity [or quality] of the medicine).
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:14:32 GMT
Koko tanna, koko o so, a pa ekuro, ao ri ekuro ta. Igba wo waa ni ebi o ni pa omo agbe bayi o.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:15:58 GMT
Oro to baa dani loju kii tun nkoni leenu.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:16:54 GMT
Ojo npa'yo inu ori ndun, ki ori ma dun'nu mo nitori oorun nbo wa ran.
|
|
|
Post by Ogbeni Ogunnaike on May 18, 2016 13:17:02 GMT
Koko tanna, koko o so, a pa ekuro, ao ri ekuro ta. Igba wo waa ni ebi o ni pa omo agbe bayi o. Kini itumo apola yii ninu gbolohun?
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:18:30 GMT
Eniti aselore tio dupe, gege bi olosa koni ni eru loni.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:20:48 GMT
Koko tanna, koko o so, a pa ekuro, ao ri ekuro ta. Igba wo waa ni ebi o ni pa omo agbe bayi o. Kini itumo apola yii ninu gbolohun? Koko (coco yam) tanna(yesterday)
|
|
|
Post by Ogbeni Ogunnaike on May 18, 2016 13:22:35 GMT
Eniti aselore tio dupe, gege bi olosa koni ni eru loni. Bi e se n ko Ede Yoruba n pa mi ni erin. E n ko'o sile bi e se n so'o. Fun opo awon eniyan, ko ni se'e ka. Eni ti a se ni ore (l'ore) ti ko (o) dupe, gege bi olosa ko eni l'eru lo ni.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:22:44 GMT
emasope ki omode madete tobati le dagbo gbe.
|
|
|
Post by Ogbeni Ogunnaike on May 18, 2016 13:23:27 GMT
Kini itumo apola yii ninu gbolohun? Koko (coco yam) tanna(yesterday) Ehen... o sese ye mi ni bayii. E o ba ti ni wipe. "Koko ti ana" yala tabi dipo "koko tanna".
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:25:26 GMT
Koko (coco yam) tanna(yesterday) Ehen... o sese ye mi ni bayii. E o ba ti ni wipe. "Koko ti ana" yala tabi dipo "koko tanna". I'll try and type them properly.
|
|
|
Post by Ogbeni Ogunnaike on May 18, 2016 13:26:09 GMT
emasope ki omode madete tobati le dagbo gbe. E maa so pe ki omode maa dete. Ti o ba ti .... " Dagbo gbe" kini eyi tunmo si?
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:27:21 GMT
Odo to t'oju eni kun, k'ole gbe ni lo.
|
|
|
Post by Ogbeni Ogunnaike on May 18, 2016 13:27:51 GMT
Ehen... o sese ye mi ni bayii. E o ba ti ni wipe. "Koko ti ana" yala tabi dipo "koko tanna". I'll try and type them properly. E maa so wipe wahala temi po o. Emi kan n fun yin ni imoran ni o. E ku ise.
|
|
|
Post by Belmot on May 18, 2016 13:30:12 GMT
emasope ki omode madete tobati le dagbo gbe. E maa so pe ki omode maa dete. Ti o ba ti .... " Dagbo gbe" kini eyi tunmo si? Not ti o ba, it is to ba ti le d'agbo gbe.
|
|